back to all blogs

All Blogs

Ṣe àfiránsẹ́ risiti sí àwọn oníbárà tí wọ́n bá ti san owó

Jun 2022

4 mins read

Yoruba

Ṣe àfiránsẹ́ risiti sí àwọn oníbárà tí wọ́n bá ti san owó

Dillali ń ṣe àbójútó gbogbo àkọọlẹ̀ owó ìṣowò rẹ láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin! Báyìí ni Dillali ṣe le ràn ọ́ lọ́wọ́ nínú ìṣowò rẹ :

  • Ṣe àfiránsẹ́ àwọn ìwé risiti sí àwọn oníbárà lórí ẹ̀rọ ayélujára Whatsapp ni ìṣẹ́jú wínníwínní.
  • Ṣe àkọọlẹ̀ àwọn ọjà títà, owó tó ń wọlé àti ìnáwó rẹ lọ́gán.
  • Ṣe àkóso àlàyé àwọn oníbárà rẹ ní ojú kan
  • Ṣe àfiránsẹ́ risiti sí àwọn oníbárà tí wọ́n bá ti san owó
  • Fi ìrọ̀rùn ṣe àfiránsẹ́ olùránnilétí sí àwọn tó jẹ ọ́ lówó.
  • Wo bí òwò ṣe ń lọsíwájú lósoosù pẹ̀lú àlàyé àkọọlẹ̀ tó péye Dillali
  • Ṣe àkóso ìnáwó rẹ pẹ̀lú ìrọ̀rùn yálà ní èdè Haúsá, Igbo, tàbí Yorùbá

Má ṣe pàdánù èyí! Darapọ̀ mọ́ àwọn bíi ẹgbẹ̀rún mọ́kànlà ìṣowò tí ó ń ṣe àmọ́jútó ìṣowò wọn pẹ̀lú Dillali lọfẹ. Ṣe àgbàsílè ẹ̀rọ Dillali láti orí ẹ̀rọ ayélujára Google Playstore àti Appstore láti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àkóso àwọn ìnáwó rẹ lónìí lọfẹ.

Bẹ̀rẹ̀ nísinsìnyí lọfẹ