back to all blogs

All Blogs

Tọpa owó tó ń wọlé àti ìnáwó òwò rẹ lọfẹ. Pẹ̀lú Dillali

Jun 2022

4 mins read

Yoruba

Tọpa owó tó ń wọlé àti ìnáwó òwò rẹ lọfẹ. Pẹ̀lú Dillali

Ká àbọ̀ sí orí Dillali, ohun èlò òwò tó rọrùn tó ń ṣe ìrànwọ́ láti tọpa owó tó ń wọlé àti ìnáwó òwò rẹ lọfẹ. Pẹ̀lú Dillali, ó lè fi ìrọ̀rùn tọpa àwọn ọjà títà rẹ kí o sì ṣe àfi múlẹ̀ àwọn àkọọlẹ̀ rẹ. Ṣe àbójútó àwọn ìgbàsílè ìṣowò re. ​​

Dillali ni:

  • Ni ààbò, ní ìrọ̀rùn, ní kíákíá
  • O lè rí gbogbo èrè tí ò ń jẹ àti iye tí òun ná ní ojú kan lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.
  • O kò nílò ìṣirò rárá

Bẹ̀rẹ̀ nísinsìnyí lọfẹ